Àwọn Ọba Keji 18:18 BM

18 Nígbà tí wọ́n ké sí Hesekaya ọba, Eliakimu, ọmọ Hilikaya tí ó ń ṣe àkóso ààfin, ati Ṣebina akọ̀wé ọba, ati Joa ọmọ Asafu, tí ń ṣe àkóso ìwé ìrántí ni wọ́n jáde sí wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 18

Wo Àwọn Ọba Keji 18:18 ni o tọ