Àwọn Ọba Keji 18:23 BM

23 Nisinsinyii, ẹ wá ṣe àdéhùn pẹlu ọba Asiria, oluwa mi. N óo fun yín ní ẹgbaa (2,000) ẹṣin bí ẹ bá lè rí ẹgbaa (2,000) eniyan tí yóo gùn wọ́n.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 18

Wo Àwọn Ọba Keji 18:23 ni o tọ