Àwọn Ọba Keji 18:25 BM

25 Ṣé o rò pé lásán ni mo wá láti pa ilẹ̀ yìí run, láìsí ìrànlọ́wọ́ OLUWA? OLUWA fúnra rẹ̀ ni ó sọ fún mi pé kí n wá pa ilẹ̀ yìí run.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 18

Wo Àwọn Ọba Keji 18:25 ni o tọ