Àwọn Ọba Keji 18:28 BM

28 Nígbà náà ni Rabuṣake kígbe sókè rara ní èdè Heberu tíí ṣe èdè àwọn ará Juda ó ní, “Ẹ gbọ́ ohun tí ọba Asiria ń sọ fun yín;

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 18

Wo Àwọn Ọba Keji 18:28 ni o tọ