Àwọn Ọba Keji 18:35 BM

35 Nígbà wo ni ọ̀kan ninu àwọn ọlọrun orílẹ̀-èdè wọnyi gba orílẹ̀-èdè wọn lọ́wọ́ ọba Asiria rí, tí OLUWA yóo fi gba Jerusalẹmu lọ́wọ́ mi?”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 18

Wo Àwọn Ọba Keji 18:35 ni o tọ