Àwọn Ọba Keji 18:37 BM

37 Nígbà náà ni Eliakimu, tí ń ṣe àkóso ààfin ati Ṣebina, akọ̀wé ọba, ati Joa, tí ń ṣe àkóso ìwé ìrántí fa aṣọ wọn ya láti fi ìbànújẹ́ wọn hàn, wọ́n sì lọ sọ ohun tí olórí ogun náà wí fun ọba.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 18

Wo Àwọn Ọba Keji 18:37 ni o tọ