Àwọn Ọba Keji 19:26 BM

26 Nítorí náà ni àwọn tí wọn ń gbé inú àwọn ìlú olódi náà ṣe di aláìlágbára,tí ẹ̀rù sì bà wọ́n gidigidi.Wọ́n dàbí ìgbà tí atẹ́gùn gbígbóná ìlà oòrùnbá fẹ́ lu koríko tabi ewéko tí ó hù ní orí òrùlé.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 19

Wo Àwọn Ọba Keji 19:26 ni o tọ