Àwọn Ọba Keji 19:3 BM

3 Wọ́n sì jíṣẹ́ Hesekaya ọba fún Aisaya pé, “Ọba sọ pé òní jẹ́ ọjọ́ ìrora, wọ́n ń fi ìyà jẹ wá, a sì wà ninu ìtìjú. A dàbí aboyún tí ó fẹ́ bímọ ṣugbọn tí kò ní agbára tó.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 19

Wo Àwọn Ọba Keji 19:3 ni o tọ