Àwọn Ọba Keji 19:32 BM

32 “Ohun tí OLUWA sọ nípa ọba Asiria ni pé, kò ní wọ inú ìlú yìí, bẹ́ẹ̀ ni kò ní ta ọfà kankan sí i. Kò sí ọmọ ogun kan tí ó ní apata tí yóo wá sí ẹ̀bá ìlú náà, bẹ́ẹ̀ ni kò ní lè gbìyànjú láti gbógun tì í.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 19

Wo Àwọn Ọba Keji 19:32 ni o tọ