Àwọn Ọba Keji 19:7 BM

7 Ó ní òun óo fi ẹ̀mí kan sinu rẹ̀, tí yóo mú kí ó sá pada sí ilẹ̀ rẹ̀ nígbà tí ó bá gbọ́ ìròyìn kan, òun óo sì jẹ́ kí wọ́n pa á nígbà tí ó bá dé ilẹ̀ rẹ̀.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 19

Wo Àwọn Ọba Keji 19:7 ni o tọ