Àwọn Ọba Keji 19:9 BM

9 Nígbà tí ọba Asiria gbọ́ pé Tirihaka, ọba Etiopia, ń kó ogun rẹ̀ bọ̀ láti bá òun jagun, ó ranṣẹ sí Hesekaya, ọba Juda, ó ní kí wọ́n sọ fún un pé,

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 19

Wo Àwọn Ọba Keji 19:9 ni o tọ