Àwọn Ọba Keji 2:17 BM

17 Ṣugbọn wọ́n rọ̀ ọ́ títí tí ojú fi ń tì í, ó sì wí fún wọn pé, “Ẹ rán wọn lọ.” Wọ́n bá rán àwọn aadọta ọkunrin lọ, wọ́n wá Elija ní àwọn orí òkè ati àwọn àfonífojì fún ọjọ́ mẹta, ṣugbọn wọn kò rí i.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 2

Wo Àwọn Ọba Keji 2:17 ni o tọ