Àwọn Ọba Keji 2:2 BM

2 Elija sọ fún Eliṣa pé, “Dúró níhìn-ín nítorí pé OLUWA rán mi sí Bẹtẹli.”Ṣugbọn Eliṣa dáhùn pé, “Bí OLUWA ti wà láàyè tí ìwọ náà sì wà láàyè, n kò ní fi ọ́ sílẹ̀.” Nítorí náà wọ́n jọ lọ sí Bẹtẹli.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 2

Wo Àwọn Ọba Keji 2:2 ni o tọ