Àwọn Ọba Keji 2:21 BM

21 Lẹ́yìn náà, ó jáde lọ sí ibi orísun omi náà, ó da iyọ̀ náà sí i, ó sì wí pé, “Báyìí ni OLUWA wí, ‘Mo sọ omi yìí di ọ̀tun lónìí, kò ní fa ikú mọ́, bẹ́ẹ̀ ni kò ní ba oyún jẹ́ mọ́.’ ”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 2

Wo Àwọn Ọba Keji 2:21 ni o tọ