Àwọn Ọba Keji 2:23 BM

23 Eliṣa kúrò níbẹ̀, ó lọ sí Bẹtẹli. Bí ó ti ń lọ, àwọn ọmọdekunrin kan ní ìlú náà bẹ̀rẹ̀ sí fi Eliṣa ṣe ẹlẹ́yà; wọ́n ń wí pé, “Kúrò níbí, ìwọ apárí! Kúrò níbí, ìwọ apárí!”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 2

Wo Àwọn Ọba Keji 2:23 ni o tọ