Àwọn Ọba Keji 2:4 BM

4 Elija tún sọ fún Eliṣa pé, “Dúró níhìn-ín, nítorí pé OLUWA rán mi sí Jẹriko.”Eliṣa dáhùn pé, “Bí OLUWA ti wà láàyè, tí ìwọ náà sì wà láàyè, n kò ní fi ọ́ sílẹ̀.” Nítorí náà wọ́n jọ lọ sí Jẹriko.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 2

Wo Àwọn Ọba Keji 2:4 ni o tọ