Àwọn Ọba Keji 2:6 BM

6 Elija tún sọ fún Eliṣa pé, “Dúró níhìn-ín nítorí pé OLUWA rán mi sí odò Jọdani.”Eliṣa dáhùn pé, “Bí OLUWA ti ń bẹ, tí ìwọ náà sì wà láàyè, n kò ní fi ọ́ sílẹ̀.” Nítorí náà wọ́n jọ ń lọ.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 2

Wo Àwọn Ọba Keji 2:6 ni o tọ