Àwọn Ọba Keji 20:1 BM

1 Ní àkókò kan Hesekaya ṣàìsàn tóbẹ́ẹ̀ tí ó fẹ́rẹ̀ kú. Wolii Aisaya ọmọ Amosi, wá sọ́dọ̀ rẹ̀, ó sọ fún un pé, “OLUWA ní kí o palẹ̀ ilé rẹ mọ́ nítorí pé kíkú ni o óo kú, o kò ní yè.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 20

Wo Àwọn Ọba Keji 20:1 ni o tọ