Àwọn Ọba Keji 20:17 BM

17 ‘Àkókò kan ń bọ̀ tí wọn yóo kó gbogbo ohun tí ó wà ninu ààfin rẹ lọ sí Babiloni, gbogbo ohun tí àwọn baba ńlá rẹ ti kó jọ látẹ̀yìnwá títí di òní ni wọn óo kó lọ, wọn kò ní fi nǹkankan sílẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 20

Wo Àwọn Ọba Keji 20:17 ni o tọ