Àwọn Ọba Keji 20:19 BM

19 Hesekaya sọ fún Aisaya pé, “Ọ̀rọ̀ OLUWA tí o sọ dára.” Nítorí ó wí ninu ara rẹ̀ pé, alaafia ati ìfọ̀kànbalẹ̀ yóo sá wà ní àkókò tòun.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 20

Wo Àwọn Ọba Keji 20:19 ni o tọ