Àwọn Ọba Keji 20:6 BM

6 n óo sì jẹ́ kí ó gbé ọdún mẹẹdogun sí i. N óo gba òun ati Jerusalẹmu lọ́wọ́ ọba Asiria. N óo sì dáàbò bo ìlú yìí nítorí tèmi fúnra mi ati nítorí ìlérí tí mo ṣe fún Dafidi, iranṣẹ mi.’ ”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 20

Wo Àwọn Ọba Keji 20:6 ni o tọ