Àwọn Ọba Keji 21:13 BM

13 Ó ní òun óo jẹ Jerusalẹmu níyà bí òun ti jẹ Samaria níyà. Ó ní bí òun ti ṣe sí ìdílé Ahabu ati àwọn ọmọ rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni òun óo gbá àwọn eniyan náà kúrò ní Jerusalẹmu, bí àwo tí a nù tí a sì da ojú rẹ̀ bolẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 21

Wo Àwọn Ọba Keji 21:13 ni o tọ