Àwọn Ọba Keji 21:19 BM

19 Ẹni ọdún mejilelogun ni Amoni nígbà tí ó jọba, ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún meji. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Meṣulemeti ọmọ Harusi ará Jotiba.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 21

Wo Àwọn Ọba Keji 21:19 ni o tọ