Àwọn Ọba Keji 21:9 BM

9 Ṣugbọn àwọn ọmọ ilẹ̀ Juda kò júbà OLUWA, Manase sì mú kí wọ́n dẹ́ṣẹ̀ tí ó burú ju èyí tí àwọn eniyan ilẹ̀ náà tẹ́lẹ̀ dá lọ, àní, àwọn tí OLUWA lé jáde kúrò níwájú àwọn ọmọ Israẹli.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 21

Wo Àwọn Ọba Keji 21:9 ni o tọ