Àwọn Ọba Keji 22:13 BM

13 “Ẹ lọ bèèrè ohun tí a kọ sinu ìwé yìí lọ́wọ́ OLUWA fún èmi ati fún gbogbo eniyan Juda. OLUWA ń bínú sí wa gidigidi nítorí pé àwọn baba ńlá wa kò ṣe ohun tí ìwé yìí pa láṣẹ fún wa.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 22

Wo Àwọn Ọba Keji 22:13 ni o tọ