Àwọn Ọba Keji 22:7 BM

7 Ó ní àwọn tí wọ́n ń ṣe àkóso àtúnṣe ilé náà kò ní nílò láti ṣe ìṣirò owó tí wọn ń ná, nítorí pé gbogbo wọn ni wọ́n jẹ́ olóòótọ́.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 22

Wo Àwọn Ọba Keji 22:7 ni o tọ