Àwọn Ọba Keji 23:18 BM

18 Josaya bá pàṣẹ pé kí wọ́n fi sílẹ̀ bí ó ti wà, kí wọ́n má ṣe kó egungun rẹ̀.Nítorí náà, wọn kò kó egungun rẹ̀ ati egungun wolii tí ó wá láti Samaria.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 23

Wo Àwọn Ọba Keji 23:18 ni o tọ