Àwọn Ọba Keji 23:20 BM

20 Ó pa gbogbo àwọn alufaa ibi ìrúbọ lórí pẹpẹ ìrúbọ wọn, ó sì jó egungun eniyan lórí gbogbo àwọn pẹpẹ ìrúbọ náà. Lẹ́yìn náà, ó pada sí Jerusalẹmu.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 23

Wo Àwọn Ọba Keji 23:20 ni o tọ