Àwọn Ọba Keji 23:6 BM

6 Ó kó gbogbo àwọn ère oriṣa Aṣera tí ó wà ninu ilé OLUWA lọ sí àfonífojì Kidironi lẹ́yìn Jerusalẹmu. Ó sun wọ́n níná níbẹ̀, ó lọ̀ wọ́n lúbúlúbú, ó sì fọ́n eérú wọn ká sórí ibojì àwọn eniyan.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 23

Wo Àwọn Ọba Keji 23:6 ni o tọ