Àwọn Ọba Keji 24:4 BM

4 ati nítorí ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ tí ó ti ta sílẹ̀, nítorí tí ó ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀ ní gbogbo ìgboro Jerusalẹmu, OLUWA kò ní dáríjì í.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 24

Wo Àwọn Ọba Keji 24:4 ni o tọ