Àwọn Ọba Keji 25:24 BM

24 Gedalaya bá búra fún wọn, ó ní: “Ẹ má ṣe bẹ̀rù nítorí àwọn olórí Kalidea, ẹ máa gbé ilẹ̀ náà kí ẹ sì máa sin ọba Babiloni, yóo sì dára fun yín.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 25

Wo Àwọn Ọba Keji 25:24 ni o tọ