Àwọn Ọba Keji 25:26 BM

26 Ni gbogbo wọn, àtọmọdé, àtàgbà, ati àwọn olórí ogun bá gbéra, wọ́n kó lọ sí Ijipti, nítorí ẹ̀rù àwọn ará Kalidea bà wọ́n.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 25

Wo Àwọn Ọba Keji 25:26 ni o tọ