Àwọn Ọba Keji 25:28 BM

28 Ó bá a sọ̀rọ̀ rere, ó sì fi sí ipò tí ó ga ju ti gbogbo àwọn ọba tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀ ní Babiloni lọ.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 25

Wo Àwọn Ọba Keji 25:28 ni o tọ