Àwọn Ọba Keji 25:7 BM

7 Wọ́n pa àwọn ọmọ Sedekaya lójú rẹ̀, lẹ́yìn náà ni Nebukadinesari ọba yọ ojú Sedekaya, ó fi ẹ̀wọ̀n dè é, ó sì mú un lọ sí Babiloni.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 25

Wo Àwọn Ọba Keji 25:7 ni o tọ