Àwọn Ọba Keji 3:11 BM

11 Ó bá bèèrè pé, “Ṣé kò sí wolii OLUWA kan níhìn-ín tí ó lè bá wa wádìí lọ́wọ́ OLUWA?”Ọ̀kan ninu àwọn iranṣẹ Joramu bá dáhùn pé, “Eliṣa ọmọ Ṣafati, tí ó jẹ́ iranṣẹ Elija, wà níhìn-ín.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 3

Wo Àwọn Ọba Keji 3:11 ni o tọ