Àwọn Ọba Keji 3:19 BM

19 Ẹ óo ṣẹgun àwọn ìlú olódi ati àwọn ìlú dáradára wọn, ẹ óo gé gbogbo igi dáradára, ẹ ó dí gbogbo orísun omi wọn; ẹ óo sì da òkúta sí gbogbo ilẹ̀ oko wọn.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 3

Wo Àwọn Ọba Keji 3:19 ni o tọ