Àwọn Ọba Keji 3:22 BM

22 Nígbà tí wọ́n jí ní òwúrọ̀ ọjọ́ keji, tí oòrùn ń ràn sórí omi náà, àwọn ará Moabu rí i pé omi tí ó wà níwájú àwọn pọ́n bí ẹ̀jẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 3

Wo Àwọn Ọba Keji 3:22 ni o tọ