Àwọn Ọba Keji 3:24 BM

24 Ṣugbọn nígbà tí wọ́n dé ibùdó-ogun náà, àwọn ọmọ ogun Israẹli kọlù wọ́n, títí tí wọ́n fi sá pada; wọ́n sì ń pa wọ́n ní ìpakúpa bí wọ́n ti ń lé wọn lọ.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 3

Wo Àwọn Ọba Keji 3:24 ni o tọ