Àwọn Ọba Keji 3:26 BM

26 Nígbà tí ọba Moabu rí i pé ogun náà le pupọ, ó mú ẹẹdẹgbẹrin (700) ọkunrin tí wọ́n ń lo idà, ó gbìyànjú láti la ààrin ogun kọjá níwájú ọba Edomu, ṣugbọn kò ṣeéṣe.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 3

Wo Àwọn Ọba Keji 3:26 ni o tọ