9 Ni Joramu, ati ọba Juda ati ọba Edomu bá gbéra láti lọ sójú ogun. Lẹ́yìn tí wọ́n ti rìn fún ọjọ́ meje, kò sí omi mímu mọ́ fún wọn ati fún àwọn ẹranko tí wọ́n ru ẹrù wọn.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 3
Wo Àwọn Ọba Keji 3:9 ni o tọ