Àwọn Ọba Keji 4:31 BM

31 Ó lọ fi ọ̀pá Eliṣa lé ọmọ náà lójú, ṣugbọn ọmọ náà kò jí. Ó bá pada lọ sọ fún Eliṣa pé ọmọ náà kò jí.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 4

Wo Àwọn Ọba Keji 4:31 ni o tọ