Àwọn Ọba Keji 5:11 BM

11 Ṣugbọn Naamani fi ibinu kúrò níbẹ̀, ó ní, “Mo rò pé yóo jáde wá, yóo gbadura sí OLUWA Ọlọrun rẹ̀, yóo fi ọwọ́ rẹ̀ pa ibẹ̀, yóo sì ṣe àwòtán ẹ̀tẹ̀ náà ni.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 5

Wo Àwọn Ọba Keji 5:11 ni o tọ