16 Ṣugbọn Eliṣa dáhùn pé, “Mo fi OLUWA tí mò ń sìn búra pé n kò ní gba nǹkankan lọ́wọ́ rẹ.”Naamani rọ̀ ọ́ kí ó gbà wọ́n, ṣugbọn ó kọ̀.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 5
Wo Àwọn Ọba Keji 5:16 ni o tọ