Àwọn Ọba Keji 5:20 BM

20 nígbà tí Gehasi, iranṣẹ Eliṣa, sọ ninu ara rẹ̀ pé, “Olúwa mi jẹ́ kí Naamani ará Siria yìí lọ láì gba ohun tí ó mú wá lọ́wọ́ rẹ̀. Mo fi OLUWA búra pé, n óo sáré tẹ̀lé e láti gba nǹkan lọ́wọ́ rẹ̀.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 5

Wo Àwọn Ọba Keji 5:20 ni o tọ