Àwọn Ọba Keji 5:23 BM

23 Naamani sì rọ̀ ọ́ kí ó gba ìwọ̀n talẹnti meji. Ó di owó náà sinu àpò meji pẹlu aṣọ meji. Ó pàṣẹ fún iranṣẹ meji kí wọ́n bá Gehasi gbé wọn lọ.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 5

Wo Àwọn Ọba Keji 5:23 ni o tọ