Àwọn Ọba Keji 5:6 BM

6 ó bá lọ sí ọ̀dọ̀ ọba Israẹli pẹlu ìwé náà. Ohun tí wọ́n kọ sinu ìwé náà nìyí, “Ẹni tí ó mú ìwé yìí wá ni Naamani, iranṣẹ mi, mo rán an wá sọ́dọ̀ rẹ kí o lè wò ó sàn ninu àrùn ẹ̀tẹ̀ rẹ̀.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 5

Wo Àwọn Ọba Keji 5:6 ni o tọ