Àwọn Ọba Keji 5:8 BM

8 Nígbà tí Eliṣa gbọ́ pé ọba Israẹli ti fa aṣọ rẹ̀ ya, ó ranṣẹ sí i pé, “Kí ló dé tí o fi fa aṣọ rẹ ya? Mú ọkunrin náà wá sọ́dọ̀ mi, kí ó lè mọ̀ pé wolii kan wà ní Israẹli.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 5

Wo Àwọn Ọba Keji 5:8 ni o tọ