Àwọn Ọba Keji 6:12 BM

12 Ọ̀kan ninu wọn dáhùn pé, “Kò sí ẹnìkan ninu wa tí ń sọ àṣírí fún ọba Israẹli. Wolii Eliṣa ní ń sọ fún un, títí kan gbogbo ohun tí ẹ bá sọ ní kọ̀rọ̀ yàrá yín.”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 6

Wo Àwọn Ọba Keji 6:12 ni o tọ