Àwọn Ọba Keji 6:14 BM

14 ó rán ọpọlọpọ àwọn ọmọ ogun ati ẹṣin ati kẹ̀kẹ́-ogun lọ sibẹ. Ní òru ni wọ́n dé ìlú náà, wọ́n sì yí i po.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 6

Wo Àwọn Ọba Keji 6:14 ni o tọ