Àwọn Ọba Keji 6:21 BM

21 Nígbà tí ọba Israẹli rí wọn, ó bi Eliṣa pé, “Ṣé kí n pa wọ́n, oluwa mi, ṣé kí n pa wọ́n?”

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Keji 6

Wo Àwọn Ọba Keji 6:21 ni o tọ